2023
◄ |
Ọ̀rúndún 20k |
Ọ̀rúndún 21k
◄◄ |
◄ |
2019 |
2020 |
2021 |
2022 |
2023
Odun 2023 jẹ́ ọdún tí a wà lọ́wọ́ nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì. Ọdún 2023 bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ Àìkú nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì.
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Oṣù kínní[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- Ọjọ́ kínní oṣù kínní(Jan 1):
- Orílè-èdè Croatia bẹ̀rẹ̀ sí ún lo owó Euro.[1]
- A se ìbúra-wọlé fún Luiz Inácio Lula da Silva gẹ́gẹ́ bi ààrẹ orílè-èdè Brazil.[2]
- Ọjọ́ Kàrún oṣù kinni(Jan 5)– Orílè-èdè Vatican ṣe ìsìnkú Pópù Benedict XVI.[3]
- Ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní(Jan 8)
- Àjàkáyé-àrùn Covid 19: Orílè-èdè China ṣí ààlà ilẹ̀ wọn fún àwọn àlejò láti orílè-èdè míràn, èyí jẹ́ òpin sí fífi òfin de àwọn ìrìn àjò kọ̀kan èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹta ọdún 2020.[4][5]
- Ìdìbọ̀ sí ilé ìgbìmò asofin ti orílè-èdè Benin wáyé.[6]
- Ọjọ́ kẹtàlá sí ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kínní(Jan 13 – Jan 14) – Ipele àkọ́kọ́ ti Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Czech wáyé.[7]
- Ọjọ́ keedogun oṣù kínní(Jan 15)– Ọkọ̀ bàlúù kan tí wón ń pè ní Yeti Airlines Flight 691 já ní Pokhara, orílè-èdè Nepal, ó sì pa ó kéré jù, ènìyàn kandinladorin.[8]
- Ọjọ́ kerindínlógún oṣù kínní(Jan 16) – Ọwọ́ ìjọba orílè-èdè Italy tẹ olórí ẹgbẹ jàndùkú kan tí wón ti ún wá fún ọjọ́ pípé, Matteo Messina Denaro ní Palermo, Sicily.[9]
- Ọjọ́ ogún oṣù kínní(Jan 20)– Àwọn asọ̀fin orílè-èdè Trínídád àti Tòbágò yan Christine Kangaloo gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè náà.[10]
- Ọjọ́ keedogbon oṣù kínní(Jan 25)– Chris Hipkins rọ́pò Jacinda Ardern gẹ́gẹ́ bi Mínísítà àgbà orílè-èdè New Zealand,[11] ọjọ́ mefa lẹ́yìn tí Jacinda Ardern kọ̀wé fi ipò mínísítà àgbà sílè.[12]
- Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n sí ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kínní (Jan 27–28) – Ipele kejì Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Czech ọdun 2023 wáyé, Petr Pavel ni ó jáwé olúborí.[13]
Oṣù Kejì[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ótún le ka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àwọn Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Croatia set to join the euro area on 1 January 2023: Council adopts final required legal acts". European Council/Council of the European Union. July 12, 2022. Retrieved July 16, 2022.
- ↑ Watson, Katy (January 1, 2023). "Lula sworn in as Brazil president as Bolsonaro flies to US". BBC News. Retrieved January 1, 2023.
- ↑ "Pope Francis to lead funeral for Benedict XVI, a first in modern history". France 24 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ "China reopens borders as lunar new year travel kicks off amid Covid surge". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 January 2023. Retrieved 8 January 2023.
- ↑ "Zero-Covid over, Chinese travellers swing into overseas holiday mode". South China Morning Post (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 January 2023. Retrieved 8 January 2023.
- ↑ Linkpon, Stanislas (2022-11-09). "Législatives 2023 : plus de 6,6 millions électeurs inscrits sur la liste électorale". ORTB (in Èdè Faransé). Retrieved 2022-12-08.
- ↑ televize, Česká. "Prezidentské volby 2023". ČT24 - Nejdůvěryhodnější zpravodajský web v ČR - Česká televize (in Èdè Seeki). Retrieved 2023-01-13.
- ↑ [1]
- ↑ Italy's most-wanted mafia boss Matteo Messina Denaro arrested in Sicily. BBC
- ↑ Alexander, Gail. "Kangaloo is President-elect". www.guardian.co.tt (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-21.
- ↑ McClure, Tess (22 January 2023). "New Zealand: Chris Hipkins taking over from Jacinda Ardern on Wednesday". The Guardian. https://www.theguardian.com/world/2023/jan/22/new-zealand-labour-caucus-votes-in-chris-hipkins-to-succeed-jacinda-ardern.
- ↑ "Jacinda Ardern resigns: Reactions from around the world". RNZ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-01-19. Retrieved 2023-01-25.
- ↑ televize, Česká. "Prezidentské volby 2023". ČT24 - Nejdůvěryhodnější zpravodajský web v ČR - Česká televize (in Èdè Seeki). Retrieved 2023-01-29.