Ojúewé Àkọ́kọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Genevieve Nnaji ní ọjọ́ tó sí ilé ìránso St.Genevieve rẹ̀ ní Èkó, Nàìjíríà, May 2008

Genevieve Nnaji jẹ́ òṣeré filmu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ní 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣeré Obìnrin Dídárajùlọ. Ìlú Èkó ni Genevieve Nnaji ti dàgbà. Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀. Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́. Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní Yaba, lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí Yunifásítì ìlú Èkó. Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood. Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n Ripples nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8. Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí tó jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ OMO. Ní 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá wá fun. Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ filmu ni Naijiria pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ Most Wanted. Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmu bíi Last Party, Mark of the Beast àti Ijele. Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood. Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tódárajùlọ fún 2001 ní City People Awards, ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin tó dára jùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà. (ìtẹ̀síwájú...)

Ọjọ́ 12 Oṣù Kejìlá: Independence Day ni Kenya (1963)

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

Àwọn aláìsí lóòní...

Ọjọ́ míràn: 10 · 11 · 12 · 13 · 14 | ìyókù...



Toni Morrison.jpg



Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
Porte musc perspective 5.jpg

Agbárí Àgbọ̀nrín Olóòrúúndídùn tará Sàíbéríà.

Wikimedia logo family complete.svg Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn
Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:
Wikiàyásọ Wikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ
Wikiatúmọ̀èdè Wikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè
Wikispecies Wikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá
Wikiìròyìn Wikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀
Wikisource Wikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́
Commons Wikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò
Wikifásítì Wikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́
Wikiìwé Wikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́
Meta-Wiki Meta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia
Wikidata Wikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́