Japan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Japan
Shinjitai: 日本国
Kyujitai: 日本國

Nippon-koku or Nihon-koku
Àsìá Edìdí Ọba
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèKimigayo (君が代?)
Government Seal:
Seal of the Office of the Prime Minister and the Government of Japan
Paulownia (五七桐 Go-Shichi no Kiri?)
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Tokyo (de facto)
35°41′N 139°46′E / 35.683°N 139.767°E / 35.683; 139.767
Èdè àlòṣiṣẹ́ None[1]
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Aynu itak, Eastern Japanese, Western Japanese, Ryukyuan, and several other Japanese dialects
National language

National Scripts


Japanese

Kanji
Hiragana
Katakana
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  98.5% Japanese, 0.5% Korean, 0.4% Chinese, 0.6% other[2]
Orúkọ aráàlú Ará Japan
Ìjọba Parliamentary democracy with constitutional monarchy
 -  Emperor Naruhito
 -  Prime Minister Shinzo Abe
Aṣòfin National Diet
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà House of Councillors
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré House of Representatives
Formation
 -  National Foundation Day February 11, 660 BC[3] 
 -  Meiji Constitution November 29, 1890 
 -  Current constitution May 3, 1947 
 -  Treaty of
San Francisco

April 28, 1952 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 377,944 km2 [4](61st)
145,925 sq mi 
 -  Omi (%) 0.8
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2010 127,380,000[5] (10th)
 -  2006 census 127,333,002 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 337.1/km2 (36th)
873.1/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $4.159 trillion[6] (3rd)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $32,608[6] (23rd)
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $5.068 trillion[6] (2nd)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $39,731[6] (17th)
Gini  38.1 (2002)[7] 
HDI (2007) 0.960[8] (very high) (10th)
Owóníná International Symbol ¥ Pronounced (Yen)
Japanese Symbol 円 (or 圓 in Traditional Kanji) Pronounced (En) (JPY)
Àkókò ilẹ̀àmùrè JST (UTC+9)
 -  Summer (DST) not observed (UTC)
Ìdá ọjọ́ọdún yyyy-mm-dd
yyyy年m月d日
Era yy年m月d日 (CE−1988)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .jp
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 81

Japan (日本 Nihon or Nippon?, officially 日本国 Ja-nippon_nihonkoku.ogg Nippon-koku tabi Nihon-koku) jẹ́ orílẹ̀-èdè erékùṣùÌlà Oòrùn Asia. Ó pàlà pẹ̀lú Òkun Pàsífíìkì, o wa ni ilaorun Okun Japan, Saina, Ariwa Korea, Guusu Korea ati Rosia, o gun lati Okun Okhotsk ni ariwa de Okun Ilaorun Saina ati Taiwan ni guusu. Awon leta ti won fi n ko oruko Japan tumo si "orisun orun", eyi lo je idie ti a fi n pe Japan ni "Ile Iladide Orun".

Japan jẹ́ arkipelago àwọn Erékùṣù 6,852.[9] àwọn erékùṣù ibẹ̀ tí ó tóbi jùlọ ní Honshū, Hokkaidō, Kyūshū àti Shikoku, ti àpapọ̀ wọ́n jẹ́ èdè mẹ́tàdínlọ́gọ́rùún (97%) ìtóbi ilẹ̀ Japan. Opo awon erekusu wonyi je oloke, opo je onileru; fun apere, ibi gigajulo ni Japan, Oke Fuji, je onileru. Japan je orile-ede ikewa to iye awon eniyajulo, pelu awon eniyan ti won to egbegberun 128. Agbegbe Titobiju Tokyo, to ni oluilu de facto Tokyo ati awon ibile ayika re, ni o je agbegbe metropoli titobijulo lagbaye pelu iye eniyan to to egbegberun 30.

Iwadi iseoroayeijoun fihan pe awon eniyan ti ungbe ni Japan lati igba to ya bi igba Okutaijoun Oke. Igba akoko ti a ko gbo nipa oruko Japan ninu iwe akoole je ninu awon iwe itan Saina lati orundun 1k SK. Ipa latodo awon orile-ede miran je titele pelu idagbe igba pipe bo se han gbangba ninu itan Japan. Ni igbeyin orundun 19k ati 20k ijabori ninu Ogun Saina ati Japan Akoko, Ogun Rosia Japan, ati Ogun Agbaye 1k gba Japan laye lati fe ile re nigba itoja ogun. Ogun Saina ati Japan Keji odun 1937 tan titi de Ogun Agbaye 2k, to wa sopin ni 1945 leyin ijubombu atomu si Hiroshima ati Nagasaki. Lati igba atunse ibagbepo re ni 1947, Japan ti di oba onibagbepo olokan pelu obaluaye atiileasofin aladiboyan tounje Diet mu.

Alagbara itokowo ninla,[10] Japan ni o ni itokowo keta totobijulo lagbaye gegebi GIO oloruko[11] ati gegebi ifiwe agbara iraja. Bakanna o tun je atajalode kerin titobijulo ati arajalatode kerin titobijulo lagbaye. Botilejepe Japan lonibise ti jowo eto re lati gbe ogun, o di ile-ise ologun odeoni mu fun abo ati ise alafia. Leyin Singapore, Japan lo ni ipaniyan to kerejulo lagbaye.[12] Gegebi UN ati WHO se diye, Japan lo ni ireti igbeaye gigunjulo larin gbogbo awon orile-ede lagbaye. Bakanna o tun ni iku omo-owo tokerejulo keta, gegebi UN se so.[13][14]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "法制執務コラム集「法律と国語・日本語」". Legislative Bureau of the House of Councillors. Retrieved 2009-01-19. 
  2. CIA Factbook: Japan
  3. According to legend, Japan was founded on this date by the Emperor Jimmu, first emperor of Japan; it is seen as largely symbolic.
  4. "JAPAN STATISTICAL YEARBOOK 2010" (PDF). Statistics Bureau, Ministry of Internal Affairs and Communications Japan. as of October 1, 2008. p. 17.  Check date values in: |date= (help)
  5. Official Japan Statistics Bureau estimate
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 "Japan". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21. 
  7. CIA World Factbook [Gini rankings]
  8. Human Development Report 2009. The United Nations. Retrieved 5 October 2009.
  9. "Facts and Figures of Japan 2007 01: Land" (PDF). Foreign Press Center Japan. Retrieved 2009-07-04. 
  10. "World Factbook: Japan". CIA. Retrieved 15 January 2011. 
  11. Inman, James (21 January 2011). "China confirmed as World's Second Largest Economy". The Guardian. http://www.guardian.co.uk/business/2011/jan/21/china-confirmed-worlds-second-largest-economy. Retrieved 21 January 2011. 
  12. "Ninth United Nations survey of crime trends and operations of criminal justice systems" (PDF). UN Office on Drugs and Crime. pp. 1–9. Retrieved 1 December 2006. 
  13. "WHO: Life expectancy in Israel among highest in the world". Haaretz. May 2009. http://www.haaretz.com/news/who-life-expectancy-in-israel-among-highest-in-the-world-1.276618. Retrieved 15 January 2011. 
  14. "Table A.17" (PDF). United Nations World Population Prospects, 2006 revision. UN. Retrieved 15 January 2011.