Sojourner Truth

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Sojourner Truth
Sojourner truth c1870.jpg
An albumen silver print from approximately 1870 by Randall Studios
Born Isabella Baumfree
c. 1797
Swartekill, New York
Died Oṣù Kọkànlá 26 1883 (aged 86)
Battle Creek, Michigan
Occupation domestic servant, abolitionist, author
Parents James and Elizabeth Baumfree

Sojourner Truth (play /sˈɜrnər ˈtrθ/; Àdàkọ:Circa – November 26, 1883) ni oruko ti Isabella Baumfree, so ara re lati 1843 lo, obinrin ara Amerika to je apokoerure ati alakitiyan eto awon obinrin. Won bi Truth sinu oko-eru ni Swartekill, New York, sugbon o sa lo pelu omo-owo re obinrin si ominira ni 1826. Leyin to lo si ile-ejo lati gba omokunrin re pada, o di obinrin alawodudu akoko ti yio leke ninu iru esun na si alawofunfun. Oro togbajumo re to so nipa asa eleyameya, Obinrin Ha Ko Ni Mi Bi?, je ni 1851 ni Apejo Eto awon Obinrin Ohio ni Akron, Ohio. Nigba Ogun Abele, Truth ran awon omo ogun alawodudu lowo fun Union Army; leyin opin ogun, Truth gbiyanju lai niyori lati gba ile lowo ijoba apapo fun awon to sese kuro loko-eru.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]